LYRICS: MohBad – Back Side
INTRO
I feel good pararan “Imole”
Niphkeys!!
CHORUS
Nkan to gbé sẹyìn pò gan
Jésù lóle gbàwá
Jé ká lọ sé nínú yàrá
Nkan to gbé sẹyìn ò bad o
Oshá mò pé èmi ni MohBad o
Jékájọma Collabo
Àwọn guys mi ti nkọrin
Kòkó má ti bàwá
You wan dey go our Kabaa
If you wan come make we follow go
Go Yankee go Morocco
Nìshó nínú yàrá, Photographer gan ò le yàwá
Cause I’m feeling you
Ìwọ lomán mórí mi wú
Na you dey keep me cool
Dem say you don use juju
Dem say you don use kayamata
If no be their matter, Rọra gbẹ́sẹ̀ Amaka
VERSE
Òlómi I’m a full fire, our mumu fire
O baby I’m a full option, I’m a full option
If your backside be like school ọmọ
I no fit to miss ọmọ “Láíláí”
Ọmọ you be my last bus stop
I no get option
Ọrọ kan gbéni lọkàn
For you gal I no fit lock up
Anything you want just talk
Love is so sick be my doctor
CHORUS
Nkan to gbé sẹyìn pò gan “gbé sẹyìn pò gan”
Jésù lóle gbàwá “Jésù lóle gbàwá”
Jé ká lọ sé nínú yàrá “Jé ká lọ sé nínú yàrà 2x”
Nkan to gbé sẹyìn ò bad o
Oshá mò pé èmi ni MohBad o
Jékájọma Collabo
Àwọn guys mi ti nkọrin “wọn nkọrin 2x”
Kòkó má ti bàwá “yeh..Kòkó má ti bàwá”
You wan dey go our Kabaa
If you wan come make we follow go
Go Yankee go Morocco
Nìshó nínú yàrá, Photographer gan ò le yàwá
Cause I’m feeling you
Ìwọ lomán mórí mi wú “Ìwọ lomán mórí mi wú”
Na you dey keep me cool “Na you dey keep me cool 2x”
Dem say you don use juju “say you don use juju”
Dem say you don use kayamata “say you don use kayamata”
If no be their matter “If no be their matter”
Rọra gbẹ́sẹ̀ Amaka “Rọra gbẹ́sẹ̀ Amaka”
OUTRO
Ọmọ tó lówó ni ìyá wù
Málo sẹ bíi sìá gan
Tólówó tó fi ìyá lè, ótún fi bàbá lè.
“Timmy J“….